Ilumọka adẹrinposonu ati oṣere tiata obinrin, Adeyela Adebola, ti ọpọ mọ si Lizzy Jay/Ọmọ Ibadan ni o ti kede igbeyawo rẹ pẹlu Adẹrinposonu miiran, Adeyemo Adelere ti ọpọ mọ si, Baba Alariya. Igbeyawo ...