Iku o dọjọ, arun o doṣu, ọpọ eeyan lo ti n ṣedaro gbajumọ oṣere tiata kristẹni, Ọgbẹni Moses Korede Are ti ọpọ mọ si Baba Gbenro to doloogbe lana Ọjọru, ọjọ kẹrinla oṣu Kọkanla ọdun 2024 yii. Iyalẹnu ...